Ephesians 1:3

Ìbùkún ti Ẹ̀mí Mímọ́ nínú Kristi

3 aÒgo ni fún Ọlọ́run àti Baba Jesu Kristi Olúwa wa, ẹni tí ó ti bùkún wa láti inú ọ̀run wá pẹ̀lú àwọn ìbùkún ẹ̀mí gbogbo nínú Kristi.
Copyright information for YorBMYO